Nothing Special   »   [go: up one dir, main page]

Edited Reviewed Yoruba Scheme - All Classes - July 2009

Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 20

sfd\ CHILD OF PROMISE SCHOOL

YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK ( GRADE 1 – 6)

GRADE 1
SAA KIN-IN-NI (FIRST TERM)
1. Mo mi – n – mo o.

2. Ikini--Laarin ojo.

3. Alifabeeti A --- GB.

4. Orin: Kin ni mo ko soke yii o?

5. Alifabeeti: GB - O

6. Alifabeeti: O -Y

7. Alifabeeti A - Y

8. Orin - Awa soja kekere.

9. Orin - Awa soja kekere

10. Aworan kika

11. Atunyewo ise saa

12. Idanwo

13. Atunse idanwo

14. Ipari saa


GRADE 1

SAA KEJI (2ND TERM)

1. Faweli akosori (a, e, e i, o, o, u)

2. Konsonanti.

3. Konsonanti ati faweli.

4. Apapo konsonanti ati faweli.

5. Fifi alifabeeti pile oro.

6. Fifi alifabeeti pile oro.

7. Orin: Iya ni wura …..

8. Orin: Iya ni wura

9. Atunyewo ise saa.

10. Idanwo.

11. Atunse idanwo.

12. Ayeye ipari saa.


GRADE 1

SAA KETA (3RD TERM)

1. Onka: 1-5

2. Onka: 5-10

3. Ewi ---Ja itanna------------

4. Orin ---Ja itanna-----------

5. Lilo oro ni gbolohun

6. Orin: Labe igi orombo

7. Ewi - Yi ese re si apa kan.

8. Ewi - Yi ese re si apa kan (cont’d).

9. Atunyewo ise saa

10. Idanwo.

11. Atunse idanwo.

12. Ayeye ipari saa.


GRADE 2

SAA KIN-IN-NI (1ST TERM)

1. Lilo oro ni gbolohun

2. Awon ohun ti o wa ninu kilaasi

3. Yiya aworan awon ohun ti o wa ninu kilaasi

4. Awon ohun ti o wa ni ayika ile iwe

5. Awon ohun ti o wa ni ayika ile iwe

6. Orin - Ijo mojo lanaa.------

7. Ohun ti o wa ninu iyara idana.

8. Ohun ti o wa ninu iyara idana (cont’d.)

9. Iwe kika.

10. Sipeli.

11. Atunyewo ise saa

12. Idanwo

13. Atunse idanwo

14. Ipari saa


GRADE 2

SAA KEJI (2ND TERM)

1. Ojo ninu ose

2. Orin: Aiku, Aje, Isegun, abbl.

3. Orin idaraya - Eye meloo tolongo waye……..

4. Onka – 1 -10

5. Onka - 11 - 20

6. Aworan kika – Alawiiye iwe kin-in-ni eko 19.

7. Ewi – Bo oju re bi o ba ji

8. Ewi -- Bo oju re bi o ba ji

9. Atunyewo ise saa.

10. Idanwo

11, Atunse idanwo.

12. Ipari saa


GRADE 2

SAA KETA (3RD TERM)

1. Eya ara - Ti ori

2. Eya ara – Gbogbo ara.

3. Eya ara -- Gbogbo ara

4. Orin – ori mi, Ejika mi.......

5. Iwe kika – Alawiiye 1; Eko 21

6. Orisi awo – dudu, funfun…….

7. Ise sise lori awo.

8. Orin ----Bata mi a ro ko ko ka

9. Atunyewo ise saa.

10. Idanwo.

11. Atunse idanwo.

12. Ayeye ipari saa.


GRADE 3

SAA KIN-IN-NI (1ST TERM)

1. Akoko laarin ojo-Aaro, osan, irole ati ale

2. Oruko awon ojo ninu ose

3. Onka : 1 - 10

4. Onka : 11 - 20

5. Onka : 21 -30

6. Osu inu odun.

7. Osu inu odun (cont’d)

8. Orin – Osu inu odun

9. Ounje ile wa

10. Ounje ile wa

11. Atunyewo ise saa.

12. Idanwo.

13. Atunse idanwo.

14. Ayeye ipari saa

GRADE 3

SAA KETA (3RD TERM)

1. Oro ati idakeji

2. Oro ati idakeji


3. Orin:- E ma weyin o

4. Ere idaraya: E ma weyin o…..

5. Ewi: ise loogun ise 1 – 7 lines

6. Ewi – Ise loogun ise (cont’d)

7. Ihun gbolohun - Oro oruko

8. Ise sise lori oro oruko

9. Agbeyewo ise saa keji

10. Oruko olorun

11. Oruko olorun

12. Ayeye ipari saa.


GRADE 4

SAA KIN-IN-NI (1ST TERM)

1. Silebu – Oloro meji ati meta

2. Isomoloruko: Awon ohun elo isomoloruko

3. Orin – Omo lao fi gbe / Kulumbu yeye

4. Asa isomoloruko Oruko abiso

5. Oruko amutorunwa

6.

7. Mimo aago--aago kan, aago meji---------

8. Ise sise lori aago.

9. Orin - Agogo baba mi------------

10. Orin - Agogo baba mi------------

11. Atunyewo ise saa.

12. Idanwo.

13. Atunse idanwo

14. Ayeye++++++++++++++++++++++++++++++++++ ipari saa.


GRADE 4

SAA KEJI (2ND TERM)

1. Oge sise –Itoju ara.

2. Oge sise – Ohun elo itoju ara.

3. Orin – Imototo -------

4. Awon eso nile Yoruba.

5. Aago

6. Aago

7. Orin--Kawa sile eko wa.--------

8. Ewi: Ise loogun ise-------

9. Atunyewo ise saa.

10. Idanwo.

11. Atunse idanwo.

12. Ayeye ipari saa


GRADE 4

SAA KETA (3RD TERM)

1. Orin orile ede Naijiria

2. Onka – 1 - 20

3. Onka – 21 – 30

4. Onka – 31-40

5. Ise sise lori onka.

6. Ipinle Yoruba ati Olu-ilu won

7. Iwe kika – Akotun Yoruba Eko 5

8. Orin: Ka wa sile iwe wa lakoko.

9. Atunyew o ise saa.

10. Idanwo.

11. Atunse idanwo

12. Ayeye ipari saa.


GRADE 5

SAA Keji(2nd TERM)

1. Faweli geere ati aranmupe

2. Ami ohun: Ifaara (orisi ami ti o wa)

3. Fifi ami si ori awon oro

4. Aroso: Emi

5. Aroko: Emi

6. Oro ati idakeji

7. Oro ati idakeji

8. Eje orile ede Naijiria

9. Eje orile ede Naijiria

10. Orin: Ile iwe Korona

11. Atunyewo ise saa

12. Idanwo.

13. Atunse idanwo .

14. Ayeye ipari saa


GRADE 5

SAA Kini (1st TERM)

1. Awon ohun elo igbeyawo (idana)

2. Oruko Olorun

3. Oruko Olorun

4. Eso ile Yoruba

5. Ounje ile Yoruba.

6. Ihun gbolohun-Oro apejuwe

7.

8. Ipapanu nile Yoruba.

9. Orin omode – Omo to mo iya re loju.

10. Atunyewo ise saa.

11. Idanwo

12. Atunse idanwo.

13. Ayeye ipari saa


GRADE 5

SAA KETA (3RD TERM)

1. Onka:1- 40

2. Onka – 41-50

3. Oge sise: irun didi

4. Ohun irinse atijo

5. Ohun irinse ode-oni

6. Orin: Kayode, Kayode, sare wa abbl

7. Ewi - Ewure jeran ile -----

8. Ewi - Ewure jeran ile (cont’d)

9. Atunyewo ise saa.

10. Idanwo.

11. Atunse idanwo.

12. Ayeye ipari saa.


GRADE 6

SAA KETA (3RD TERM)

1. Orin orile- ede Naijiria

2. Eje orile-ede Naijiria

3. Ami ohun (fifi ami si ori oro)

4. Akoto Yoruba ode oni.

5. Awon igi owo ni ile Yoruba (igi koko, obi abbl)

6. Iwe kika Alawiiye iwe keji Eko keji

7. Orin ---- Olurombi.

8. Orin ---- Olurombi

9. Agbeyewo ise saa.

10. Idanwo.

11. Atunse idanwo.

12. Ayeye ipari saa.


Name :___________________________________

ONKA YORUBA

1. Ookan ______________________________

2. Eeeji ______________________________

3. Eeta ______________________________

4. Eerin ______________________________

5. Aarun ______________________________

6. Eefa ______________________________

7. Eeje ______________________________

8. Eejo ______________________________

9. Eesan ______________________________

10.Eewa ______________________________3
YORUBA
ORUKO AKEKO : ______________________________________________

ORO ATI IDAKEJI (WORDS AND OPPOSITE)

ORO IDAKEJI

1 Otun Osi

2 Tobi Kere

3 Funfun Dudu

4 Okunrin Obirin

5 Baba Iya

6 Egbon Aburo

7 Ga Kuru

8 Sanra Tinrin

9 Ibere Opin

10 Le Ro

11 Oke Isale

12 Agba Omode

13 Oko Iyawo

14 Ore Ota

15 Oluko Akeko
ORUKO ABISO (NAME GIVEN AS THE PARENT WISHES)

Oluwatosin ____________________________________________________

Funmilayo ___________________________________________________

Akinjide ______________________________________________________

Modupe ____________________________________________________

Eniola _____________________________________________________

Oluwafemi __________________________________________________

Omolola ____________________________________________________

Temitayo ____________________________________________________

ORUKO AMUTORUNWA (NAME GIVEN BY SITUATION OF BIRTH)

Taiwo ____________________________________________________

Kehinde ___________________________________________________

Idowu ______________________________________________________

Alaba ____________________________________________________

Babatunde ________________________________________________

Yetunde __________________________________________________

Iyabo ____________________________________________________

Abosede ____________________________________________________

Abiona __________________________________________________

Abioja ____________________________________________________

You might also like