Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 23 Oṣù Kínní
Ìrísí
- 1656 – Blaise Pascal ṣàtẹ̀jáde àkọ́kọ́ nínú àwọn Lettres provinciales rẹ̀.
- 1719 – Ilẹ̀ọmọba Liechtenstein jẹ́ dídásílẹ̀ nínú Ilẹ̀ọbalúayé Rómù Mímọ́.
- 1967 – Ìsọ̀kan Sófíẹ́tì àti Ivory Coast ṣèdásílẹ̀ ìbáṣepọ̀ díplómáti.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1862 – David Hilbert, onímọ̀ mathimátíkì ará Jẹ́mánì (al. 1943)
- 1929 – John Charles Polanyi, ẹlẹ́bùn Nobel ará Kánádà
- 1930 – Derek Walcott (fọ́tò), ẹlẹ́bùn Nobel ará Ìwọ̀ọrùn Índísì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1744 – Giambattista Vico, amòye ará Itálíà (ib. 1668)
- 2002 – Pierre Bourdieu, onímọ̀ ọ̀rọ̀-àwùjọ ará Fránsì (ib. 1930)
- 2002 – Robert Nozick, amòye ará Amẹ́ríkà (ib. 1938)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |