Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 18 Oṣù Kejì
Ìrísí
Ọjọ́ Kejìdínlógún Oṣù Kejì 18,02: Ọjọ́ ayẹyẹ ìgbòmìnira ní orílẹ̀-èdè Gambia (1965)
- 1929 – àyájọ́ ọjọ́ àkọ́kọ́ tí wọ́n kéde
àmì-ẹ̀yẹ Academy Awards.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1745 – Àyájọ́ ọjọ́ ìbí Alessandro Volta, tí ó jẹ́ Italian physicist(al. 1827)
- 1931 – Àyájọ́ ọjọ́ ìbí Toni Morrison, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 2019)
- 1939 – Àyájọ́ ọjọ́ ìbí Claude Ake, ẹni tí ó jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ètò òṣèlú (Nigerian political scientist) (al. 1996)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 901 – Àyájọ́ ọjọ́ tíThabit ibn Qurra, ẹni tí ó jẹ́ arìnrìn-àjò inú Òṣùpá àti onímọ̀ ìṣirò (Arab astronomer and mathematician) (b. 826)
- 1535 – Àyájọ́ ọjọ́ tí Heinrich Cornelius Agrippa,ẹni tí ó jẹ́ onímọ̀ nípa ipo tí ìràwọ̀ Oju ọ̀run wà àti oniímọ̀ nípa alchemy. 'astrologer and alchemist' (b. 1486)
- 1546 – Àyájọ́ ọjọ́ tí Martin Luther,ẹni tí ó jẹ́ alátúntò ẹ̀sìn ilẹ̀ Jamaní (b. 1483)