Nothing Special   »   [go: up one dir, main page]

Jump to content

Ribonúkléù kíkan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A hairpin loop from a pre-mRNA. Highlighted are the nucleobases (green) and the ribose-phosphate backbone (blue).

Ribonúkléù kíkan tabi ásìdì ribonúkléù (ribonucleic acid) (Pípè: /raɪbɵ.njuːˌkleɪ.ɨk ˈæsɪd/), tabi RNA, je ikan ninu awon horogigun agba meta (lapapo mo DNA ati awon proteini) ti won se koko fun gbogbo iru awon ohun alaye.

Bi DNA, RNA na je dida pelu ewon gigun to unje nukleotidi. Nukleotidi kookan ni ipilenukleu (pipe nigba mi ni ipile oloponitrojin), suga ribosi kan, ati adipo oniyofosforu kan.