Serzh Sargsyan
Ìrísí
Serzh Sargsyan Սերժ Սարգսյան | |
---|---|
Aare ile Armenia | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 9 April 2008 | |
Alákóso Àgbà | Tigran Sargsyan |
Asíwájú | Robert Kocharyan |
Alakoso Agba ile Armenia | |
In office 26 March 2007 – 9 April 2008 | |
Ààrẹ | Robert Kocharyan |
Asíwájú | Andranik Margaryan |
Arọ́pò | Tigran Sargsyan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kẹfà 1954 Stepanakert, Nagorno-Karabakh AO Azerbaijan SSR, Soviet Union (now Stepankert, Nagorno-Karabakh Republic) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Republican Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Rita Sargsyan |
Alma mater | Yerevan State University |
Serzh Azati Sargsyan (Arméníà: Սերժ Ազատի Սարգսյան, ojoibi June 30, 1954[1]) ni Aare orile-ede Armenia. O bori ninu idiboya Aare Osu Keji 2008[2] o si bo si ori aga ni Osu Kerin 2008.[3] Ko ni ibatan mo Tigran Sargsyan to je Alakoso Agba ile Armenia lowo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Official biography of Serzh Sargsyan". Archived from the original on 2010-12-19. Retrieved 2010-08-08.
- ↑ "RPA nominates Serge Sargsyan for President". PanArmenian.net. 2007-11-10. http://www.panarmenian.net/news/eng/?nid=24036. Retrieved 2007-11-11.
- ↑ "Armenia: Sarkisian Sworn In As President" Archived 2008-04-22 at the Wayback Machine., Radio Free Europe/Radio Liberty, April 9, 2008.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Serzh Sargsyan |