Nothing Special   »   [go: up one dir, main page]

Jump to content

Ikechukwu Kalu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ike Kalu
Personal information
OrúkọIkechukwu Kalu
Ọjọ́ ìbí18 Oṣù Kẹrin 1984 (1984-04-18) (ọmọ ọdún 40)
Ibi ọjọ́ibíKaduna, Nigeria
Ìga1.73 m (5 ft 8 in)
Playing positionStriker, Attacking midfielder
Youth career
1998–2002Jasper United
2002–2003U.C. Sampdoria
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2003–2007A.C. Milan8(2)
2003–2004→ Aurora Pro Patria (loan)26(4)
2004–2005→ Pisa Calcio (loan)26(7)
2005–2007→ FC Chiasso48(28)
2007–2008→ U.C. Sampdoria25(10)
2008–2010AC Bellinzona21(11)
2010–2011FC Chiasso19(9)
2012Kuopion Palloseura22(9)
2013FF Jaro21(8)
2013AC Bellinzona20(10)
2014Teuta Durrës10(5)
2014–2015Singhtarua F.C.13(2)
National team
2003Nigeria
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Ikechukwu Kalu ti won bi ni ojo kejidinlogun, osu kerin ni 1984 je agbaboolu Naijiria to gba boolu gege bi Olutayo. Oruko e Ikechukwu, tunmo si "agbara oluwa”.[1]

Ise re bii a-gba-boolu

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O bere ise e ni Jasper United ni Nàìjíríà. O tewo bowe pelu U.C. Sampdoria ni summer 2002. Leyin to gba fun akoko kan ni Genoa, A.C. tewo bowe pelu ni summer 2003 pelu apapo-nini fun €1 million, ati o ri Luca Antonini sun si odi keji ni apapo-nini idaradura (fun €2 million),[2]

won ya lo si Pisa and Chiasson. O gba goolu mejidinlogbon in 44 games ni akoko meji ni Swiss second division, which saw Sampdoria recall him in summer 2007. He made his Serie A debut on 10 November 2007 against Empoli F.C.

Ni osu kefa 2008, Sampdoria gbe Kalu pada lati Milan fun €250,000 ati ni akoko yii tewo bowe pelu Paolo Sammarco fun €2.5 million.[3] Igba to tun ya, won ta a fun awon ara Swiss fun, egbe a-gba-boolu AC Bellinzona fun€400,000.[4]

  1. "Ikechukwu - Nigerian.Name". www.nigerian.name (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-05-14. 
  2. AC Milan Spa 2006 Annual Report Archived 2011-04-25 at WebCite Àdàkọ:In lang
  3. "AC Milan Group 2008 Annual Report" (PDF). AC Milan (in Italian). ca. April 2009. Archived from the original (PDF) on 14 May 2013. Retrieved 11 June 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help); Check date values in: |date= (help)
  4. U.C. Sampdoria SpA bilancio (financial report and accounts) on 31 December 2008 Àdàkọ:In lang, PDF purchased from Italian CCIAA