Dalia Grybauskaitė
Ìrísí
Dalia Grybauskaitė | |
---|---|
13th President of Lithuania | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 12 July 2009 | |
Alákóso Àgbà | Andrius Kubilius |
Asíwájú | Valdas Adamkus |
European Commissioner for Financial Programming and the Budget | |
In office 22 November 2004 – 1 July 2009 | |
Ààrẹ | José Manuel Barroso |
Asíwájú | Michaele Schreyer Marcos Kyprianou (Budget) |
Arọ́pò | Algirdas Šemeta |
European Commissioner for Education and Culture | |
In office 1 May 2004 – 11 November 2004 Serving with Viviane Reding | |
Ààrẹ | Romano Prodi |
Asíwájú | Viviane Reding |
Arọ́pò | Ján Figeľ (Education, Training, Culture and Multilingualism) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kẹta 1956 Filnius, Soviet Union (now Lituéníà) |
Alma mater | Zhdanov University Edmund A. Walsh School of Foreign Service |
Profession | Political economist |
Signature |
Dalia Grybauskaitė (pronounced Àdàkọ:IPA-lt, ojoibi 1 March 1956) je oloselu ara orile-ede Lituéníà ati lowolowo Aare ile Lituenia to bo si ori aga ni 12 Osu Keje, 2009. Teletele ohun ni Igbakeji Alakoso Oro Okere, Alakoso Eto Inawo ati Olugbimo Europe fun Eto Inawo ati Isuna. Grybauskaitė ni obinrin olori orile-ede akoko ile Lituéníà.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |