Nothing Special   »   [go: up one dir, main page]

Jump to content

Chika Ike

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chika Ike
Chika Ike
Ọjọ́ìbíChika Ike
8 Oṣù Kọkànlá 1985 (1985-11-08) (ọmọ ọdún 39)
Onitsha, Anambra, Nigeria
Iṣẹ́Actress, Humanitarian Model
Ìgbà iṣẹ́2005—present
Websitechikaike.com/

Chika 'Nancy' Ike Ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù Kọkànlá ọdún 1985. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré jáde, olókòwò, ẹlẹ́yinjú àánú 9mọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.



Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Chika ní ìlú Onitshaní [[ÌpínlẹAnambrate]ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣeré ìtàgé ní inú ilé-ìjọsìn nígbà tí ó wà ní dédé ọmọ ọdún mẹ́fà. Ó tẹ̀ siwájú láti ma ṣe model nígbà tí ó kàwé jáde ilé-ẹ̀kọ́ girama. ].[1]

Akitiyan rẹ̀ lórí iṣẹ́ òjọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ike bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré-ìtàgé rẹ̀ ní pẹrẹu ní ọdún 2005 nígbà tí ó kópa kékeré nínú eré Sweet Love. Ó aì tún kópa ribi ribi mìíràn nínú eré Bless the Child" ní ọdún kan náà. Lẹ́yìn èyí ni ó ti ń kópa gẹ́gẹ́ bí olú-èdá ìtàn ní ú àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan tí ó ti tó ọgọ́rùún. Lára àwọn eré tí ó tún ti kópa ni: ' Paradise, Mirror of Beauty, To Love a Stranger, Girls Got Reloaded, Happy Ending, Yes We Will, Anointed Queen and The Prinand nd the Princess.[2]

Ní ọdún 2007, sonimá rẹ̀ kan Mirror of Beauty'ni 'ọ́n ṣàfihàn rẹ̀ lórí n Cineworld and Odeon cinemajákè-jádò orílẹ̀-èdè U.K,.wọ́n sì yan sinimá náà mọ́ àwọn sinimá ọlọ́kan-ò-jọkan tí wọ́n fẹ́ ṣe àgbéyẹwò rẹ̀ nínú ìpàtẹ sinimá ti e Cannes filfestival, ní ọdún 2008.[3][4] Ó dá ilé-iṣẹ́ ìgbéré-jáde rẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 2014 , tí ó pè ní Chika Ike Production tí ó sì gbé eré àkọ́kọ́ jáde nílé iṣẹ́ náà tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Teacher.Ó tún ń ṣe ètò kan tí ó pè ní African Diva Reality TV Show tí ó sì jẹ́ olóòtú àgbà fún ètò náà.[5][6][7].Ní ọdún 2015, ó gbé eré kan jáde pẹ́lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé-iṣẹ́ ted with [[Rok Stídó pè ní ies like Happy Ending àti Stuck on You.[8]


Ètò ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2004, Ó dara pò mọ́ ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Ìlú Èkó (Unilag) fún ètò ẹ̀kọ́ ọlọ́dún méjì nínú ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ti human kinetics àti health education. Ó sì tún tẹ̀ siwájú ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ yí kan náà tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú rẹ̀ ní Fásitì Unilag bákan náà. Ó tún lọ kẹ́kọ̀ọ́ siwájú si ní nínú ẹ̀kọ́ eré sinimá àti ìtàgé nílé ẹ̀kọ́ New York Film Academy ní ìlú Los Angeles, ní orílẹ̀-èdè California ní ọdún 2014.[9]

Ṣiṣẹ́ Ìtọrẹ àánú rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ike dá àjọ "Help the Child" sílẹ̀ láti lè máa fi ran àwọn ọmọ aláìní . Ní ọdún 2012, ó ṣe àpèjẹ kan níbi tí ó ti gba àwọn ọmọdé tí wọ́n tó ọgọ́rùún mẹ́ta lálejò tí sì fún wọn ní ohun ìṣeré gbogbo, ètò ékọ́ ọ̀fẹ́ àti ohun ìkọ̀wé< [10]

Chika jẹ́ ẹni tí ó ma ń sọ̀rọ̀ ṣe ìpolongo nípa "Ìwà búburú nínú ìgbéyàwó" nítorí wípé ó ti ní ìrírí irú ìṣẹ́lẹ́ bẹ́ẹ̀ rí. Ní ọdún 2013, ó sọ nípa bí ó ṣe jìyà nínú ìgbéyàwó rẹ̀ tí ó ti forí ṣọ́pọ́n.[11]

Àwọn amì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Chika gba àwọn amì-ẹ̀yẹ lóríṣirí fún àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ọlọ́kan-ò-jọkan . lára rẹ̀ ni: Africa Movie Academy Awards Best Upcoming Actress, 2008, àti the Africa Movie Academy Award for Best Actress in a Supporting Role in 2009 fún ipa tí ó kó nínú eré "The Assassin".[2]

Year Event Prize Recipient Result
2008 African Movie Academy Awards Best Upcoming Actress Bless the Child Yàán
2009 African Movie Academy Awards Best Supporting Actress Assassination Yàán
2009 African Youth Society Award Best Role Model in Africa Self Gbàá
2009 City People Entertainment Awards Best Supporting Actress Self Yàán[12]
2011 Donven Club Awards Best Actress Self Gbàá[12]
2011 United Nations Messenger of Peace United Nations Youth Ambassador for Peace Self Honorary[13]
2012 African Heritage Awards Contributions to The Youth In Africa Self Gbàá
2013 HOG Award Icon of Hope Self Gbàá
2013 Actors Guild of Nigeria (AGN) Award Most Disciplined Actress Self Gbàá
2013 Cynosure Magazine Nigerian Fashion Recognition Awards Nollywood Fashion Icon of the Year Self Gbàá
2016 City People Entertainment Awards Face of Nollywood Self Yàán[14]
2016 ZAFFA Awards Best Producer Miss Teacher Yàán[15]
2016 ZAFFA Awards Best Actress Miss Teacher Yàán[15]

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Eré Ipa tí ó kó Notes
2020 Small Chops Nikita Drama
2016 Happy Ending Lape Drama, Romance
2016 Locked up Susan Drama, Romance
2015 Miss Teacher Nwanne Drama, Romance
2014 Secret Act I & II
2012 Bridge of Contract
2012 The End is Near
2010 Street President Nene
2009 Dangerous Beauty Anita
2009 Eyes of the Nun
2009 Harverst of Love Nancy
2008 Before The Rain Anita
2008 Desire Juliet
2008 Jealous Princess Mercy
2006 The Seekers Yvonne I & II
2006 White Chapel Yvonne
2006 Emotional Blunder Yvonne

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Chika Ike Biography, Nollywood Star Actress". InformAfrica.com. Archived from the original on 2017-02-02. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. 2.0 2.1 "Chika Ike Biography, Profile, Movies, Latest News & Life History | NaijaGistsBlog Nigeria, Nollywood, Celebrity ,News, Entertainment, Gist, Gossip, Inspiration, Africa". Naijagists.com. Archived from the original on 2017-01-28. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Chika Ike Making Waves In The International Scene". Modernghana.com. 2007-09-28. Archived from the original on 2017-02-02. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. . Modern Ghana. https://www.modernghana.com/movie/1729/1/mirror-of-beauty-showing-in-uk-cinemas.html. 
  5. "African Diva Reality TV show season 1 Archives". News Of Nigeria. Archived from the original on 2017-02-02. https://web.archive.org/web/20170202022857/https://newsofnigeria.com/tag/african-diva-reality-tv-show-season-1/. Retrieved 2017-01-21. 
  6. Kayode Badmus (2015-08-02). "Chika Ike begins production of new movie 'All of me' - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". Thenet.ng. Archived from the original on 2017-02-02. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Chika Ike: 5 Nollywood movies produced by actress - Movies - Pulse" (in Èdè Jámánì). Pulse.ng. 2016-11-08. Archived from the original on 2017-02-02. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Watch the Trailer for Chika Ike's New Movie "One Fine Day" | A Story of an Obsessed Ex". Bellanaija.com. 2016-06-30. Archived from the original on 2017-02-01. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. "Chika Ike graduates from LA Film School". The Nation. 2014-05-24. Archived from the original on 2017-02-02. https://web.archive.org/web/20170202034937/http://thenationonlineng.net/chika-ike-graduates-la-film-school/. Retrieved 2017-01-24. 
  10. "Chika Ike's Good Deed – Feeds Less Privileged Kids for Easter". Bellanaija.com. 2014-04-25. Archived from the original on 2017-02-01. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. Damilare Aiki (2013-08-10). "Chika Ike: "I Left My Marriage because I was a Victim of Domestic Violence" | Nollywood Actress shares Story of Physical Assault". Bellanaija.com. Archived from the original on 2016-02-03. Retrieved 2017-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  12. 12.0 12.1 "Chika Ike". Naij. Archived from the original on 2016-08-20. Retrieved 2017-01-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. Arogundade, Funsho (2012-01-05). "Chika Ike Bags UN Ambassador Award". P.M. News. Archived from the original on 2017-02-02. Retrieved 2017-01-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  14. Izuz, Chidumga (2016-11-07). "'Suru L'ere,' 'Tinsel,' Adeniyi Johnson, Mide Martins among nominees". Archived from the original on 2017-02-02. Retrieved 2017-01-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  15. 15.0 15.1 "ZAFAA 2016 Nominees". ZAFAA. Archived from the original on 2017-02-02. Retrieved 2017-01-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Àwọn Ìtàkùn ìjásòde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]