Nothing Special   »   [go: up one dir, main page]

Jump to content

Carbamoyl phosphate

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àdàkọ:Chembox KEGGÀdàkọ:Chembox MeSHName
Carbamoyl phosphate
{{{Alt}}}
{{{Alt}}}
Identifiers
CAS number 590-55-6
PubChem 278
ChEBI CHEBI:17672
SMILES
InChI
InChI key FFQKYPRQEYGKAF-UHFFFAOYSA-N
ChemSpider ID 272
Properties
Molecular formula CH2NO5P2−
Molar mass 141.020 g/mol
 Àdàkọ:Cross(what is this?)  (verify)
Except where noted otherwise, data are given for materials in their standard state (at 25 °C, 100 kPa)
Infobox references

Carbamoyl phosphate jẹ́ kẹ́míkà tí ó lágbára tí ó sì wúlò ní ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà nínú ara. Ní àwọn ẹranko tó ń gbé inú ilẹ, ó wà lágbede méjì ní ìyọ nitrogen kúrò nínú ara látàrí Ìyípo urea ìṣètò pyrimidines.

Wọ́n máa ń ṣètò rẹ latí inú bicarbonate, ammonia (tí a yọ kúrò nínú glutamine), àti phosphate (láti ATP). Enzyme carbamoyl phosphate synthetase, máa ń jẹ́ kó ṣeṣe báyì :

  • HCO3 + ATP → ADP + HO–C(O)–OPO2−3 (carboxyl phosphate)
  • HO–C(O)–OPO2−3 + NH3 + OHHPO2−4 + O–C(O)NH2 + H2O
  • O–C(O)NH2 + ATP → ADP + H2NC(O)OPO2−3

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Nelson, David L.; Cox, Michael M. Lehninger Principles of Biochemistry fourth edition. New York: W. H. Freeman and company. [<span title="Please supply an "|ISBN=" of publication, or use "|ISBN= unspecified" for intentional omission.">ISBN missing]