Fásitì Odùduwà
Oduduwa University | |
---|---|
OUI | |
Motto | Learning for human development |
Established | 2009 |
Type | Private |
Chancellor | Dr. Rahmon Adedoyin |
Vice-Chancellor | Prof. Chibuzo Nnate Nwoke |
Location | Ipetumodu, Osun State, Nigeria |
Campus | Ipetumodu |
Website | http://www.oduduwauniversity.edu.ng/ |
Fásitì Odùduwà jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ àdáni tí wọ̀n dá sílẹ̀ ní ọdún 2009. Iké-ẹ̀kọ́ náà wà ní Ilé-Ifẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. Àwọn olùgbé Ilé-Ifẹ̀ tó iye bí ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọọ́ta, ọgọ́rùún méjì ólé mọ́kàndínláàdọ́ta àti àti mọ́kàndínlọ́gọ́eùún ènìyàn (50,000-249,999). Àjọ (NUC) tí ó ń rí sí ìgbòkè-gbodò ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ fásitì nílẹ̀ Nàìjíríà fòntẹ̀ má báṣẹ́ rẹ lọ oẹ̀lú ẹ̀rí tó yanarantí tí wọ́n sì to ilé-ẹ̀kọ́ náà sí ipò kẹrìnlélọ́gọ́rùún (104) láàrín àwọn ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ikẹ̀ Nàìjíríà, nígbà tí ó wà ní ipò ẹgbẹ̀rún kan ólé ọgọ́rùn mẹ́fà àti mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n (10617) ní àwùjọ ilé-ẹ̀kọ́ àgbáyé. Fáfitì Odùduwà ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn ní ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ jákè-jádò àgbọ́ọ̀n-gbẹ ìmọ̀ lóeíṣiríṣi.Oduduwa.
Fásitì Odùduwà fìdí kalẹ̀ sí ìlú Ìpetumodù, Ilé-Ifẹ̀, ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.[1] Wọ́n forí ilé-èkọ́ náà sọ orí baba ńlá àwọn Yorùbá tí ó ń jẹ́ Odùduwà.
Àwọn ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ibẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iké-ẹ̀kọ́ náà ni ó ní àwọn ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ wọ̀nyí:
- College of Management and Social Sciences (CMSS)
- College of Natural and Applied Sciences (CNAS)
- College of Environmental Design and Management (CEDM)
- College of Engineering and Technology (CET)[2]
Ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ìmọ̀ àwùjọ, ìṣúná àti ìdókòwò (College of Management and Social Sciences (CMSS) )
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ètò ẹ̀kọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́-gboyè àkọ́kọ́ (bachelor's degree) ni wọ́n ṣe lọ́wọ́ ní abala ẹ̀ka ètọ́ ẹ̀kọ́ yí.
- Business Administration
- Mass Communication & Media Technology
- Economics
- Banking & Finance
- Accounting
- Public Administration
- Political Science
- International Relations.
Ẹ̀ka ẹtò ẹ̀kọ̀ Natural àti Applied Sciences (CNAS)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ètò ẹ̀kọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́-gboyè àkọ́kọ́ (bachelor's degree) ni wọ́n ṣe lọ́wọ́ ní abala ẹ̀ka ètọ́ ẹ̀kọ́ yí.
- Mathematics/Statistics
- Mathematics/Computer Science
- Computer Science
- Physics (Electronics)
- Chemistry
- Biochemistry
- Microbiology/Pre-medicine
- Industrial Chemistry
Ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ Environmental Design àti Management (CEDM)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Architecture
- Estate Management
- Quantity Surveying
Ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ Ìmọ̀-Ẹ̀rọ (CET)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Computer Engineering
- Electronic/Electrical Engineering
Combination is available with Computer Science
Àwọn ibùdó ìwádìí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn wọ̀nyí jẹ́ ibùdó ìwádìí ìmọ̀ nílé-ẹ̀kọ́ náà:
- Centre for Information and Communications Technology (CICT)
- Centre for Entrepreneurial and Vocational Training (CEV)
- Centre for Professional Studies (CPS)
- Centre for Cultural Studies (CCS)
- Centre for Foundation and Extra-moral Studies (CFES)
- Centre for International Studies/Exchange Programmes
- Centre for Communication and Leadership Training (CCL)
Gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ iké-ẹ̀kọ́ yí láti gba agbònrin ICT àti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ iṣẹ́ ọwọ́ (TCEVT) kọjá kí wọ́n tó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́.[3]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Oduduwa University". Ranking & Review. 2019-05-08. Retrieved 2019-06-02.
- ↑ Ibenegbu, George (2018-05-29). "Can you afford Oduduwa school fees?". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-06-02.
- ↑ ":: ODUDUWA UNIVERSITY ::". :: ODUDUWA UNIVERSITY ::. Retrieved 2019-06-02.