Nothing Special   »   [go: up one dir, main page]

Note Ejiogbe

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 13

Ejiogbe 1

Ejiogbe 1

Bi a bati ji, kamon ki olowo ori eni,


Olowo ori eni laa pe’fa,
Adifafun fun Ejiogbe,
Nigba to nawo sire gbogbo,
T’owo re o to’re gbogbo,
Won niko kara giri ebo nikose,
O gbo riru ebo o rubo,

Oni Oyeku meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Iwori meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Odi meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Irosun meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Owonrin meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Obara meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Okanran meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Ogunda meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Osa meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Ika meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Oturupon meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Otua meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,
Oni Irete meji moki o loni o
Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Ose meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Ofun meji moki o loni o


Too too dan dan,
Baba se n fori bale fun Omo,

Oni eyin o mon, wipe eni toba fori bale nii nire gbogbo.

Translation:.
When we wake, we should praise our creator
We call Ifá our creator
Casted Ifá for Ejiogbe
When he stretched hands to all goodness
But he didn't succeed in anything
He was told to do ẹbọ
And he complied

He said oyeku méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Iwori meji I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child
Odi meji I greet you today
Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Irosun méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Ọ̀wọ́nrín méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Ọ̀bàrà méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Ọkànran méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Ogunda méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Osa méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Ìkà méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Oturupon méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Otura méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Irete méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Ọ̀sẹ̀ méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Ofun méjì I greet you today


Too too dan dan
How can a father bow down to the child

Don't you know that whoever bows down has all the
goodness.

Story:
In this verse, ejiogbe stretched out for blessings but all
his effort to make his life a better one proved abortive,
he went to his Babalawo for consultation, he was told
to make sacrifices. Parts of the sacrifice that he was
advised to do was to make sure to be humble enough
to greet and respect everyone and he did, he woke
up in the morning and went to Oyeku meji’s home to
greet him. When he got there, oyeku meji was moved
by this behavior that how can his elder leave his home
to come and greet him at home. Then he shared his
wealth with him, he left and went to iwori meji's home
to greet him, iwori méjì also gave him part of his
wealth. This is how ejiogbe went around all of them
till he got to ofunmeji’s house which he also shared
wealth with Ejiogbe. By the time ejiogbe got home to
see what he’d gotten, he realised that he had gathered
wealth, even more than each of them. That was how
he continue to progress in his life.

Ẹbọ:
Eku, ẹja, abodie, àkùkọ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọtí.

Akose:
The person has to sacrifice his pride in this Odù. Even
if he's older, he should bow down to greet everyone
whether younger or older ones. Should be good to
everyone and all his blessings will come to him.

Ejiogbe 2.
Aṣọ funfun ni ń sunkún aró
Ipilẹ ọrọ ni ń sunkún èkejì tantantan
Adífáfún ẹni olúbí
Nigbati tí ń bẹ ní gbàrà esoko
Wọ́n ní ẹbọ ní kowase
Ó gbebo nibe ó rúbọ
Ẹni olúbí kìí rahun ajé
Àrìrà oko
Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko
Ẹni olúbí kìí rahun aya
Àrìrà oko
Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko
Ẹni olúbí kìí rahun ọkọ
Àrìrà oko
Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko
Ẹni olúbí kìí rahun ọmọ
Àrìrà oko
Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko
Ẹni olúbí kìí rahun ire gbogbo
Àrìrà oko
Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko.

Translation:
It is the white clothes that always cry for dye
The beginning of the words always cry for the next one
Casted Ifá for whom the king born
When he was lost and fails in life
Babalawo asked him to make sacrifice and he
complied
whom the king born does not lack riches
Arira oko
Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko
whom the king born does not lack women
Arira oko
Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko
whom the king born does not lack men
Arira oko
Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko
whom the king born does not lack children
Arira oko
Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko
whom the king born does not lack all goodness
Arira oko
Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko.

Ẹbọ: Eku 2, ẹja 2, abodie 2, àkùkọ 2, Òkété 1.

Story:
Whom the king born means a child of a king, he was
not supposed to be lacking in everything but after
his father passed away, he began to wallow in abject
poverty. He got lost in his life and doesn't know what
to do to make his life meaningful anymore because he
was lagging behind in everything thing. He went for
consultation from babaláwo and he was told to make
sacrifice which he did, akose was also done for him
and things beings to be better for him after that.

Akose:
Èwe arira
A pack of alligator pepper, grind together and mix with
Ọ̀sẹ̀. Use iyerosun to press ejiogbe on Opon Ifá (Ifá
tray) and chant this verse on it. Mix with the Ọ̀sẹ̀ and
use it bath every morning.

Ejiogbe 3:

Eji ńlá losu lọ́mọ kékeré sure wọlé


Agbaaragba ojo ni soju ọrùn dẹ̀mùdẹ̀mù
Adífáfún Ọlọ́mọ weerewe òkè apa
Èyí tóní ire tohun pé lọ́run
Wọ́n ní kó kara giri ẹbọ ni kose
Ó gbebo nibe ó rúbọ
Ǹjẹ́ àtàrí mi ń gbé gba ọlá
Ifá mi ń gbé gba ọmọ.

Translation:
It is the drizzle that made the children to rhn inside the
house
It's the heavy rain that made the clouds softly
Casted Ifá for Ọlọ́mọ weerewe (one with small
childrens) of òkè apa
That said his blessings is taking long time in heaven
He was told to make sacrifice and he complied
My orí is preparing wealth for me
My Ifá is preparing children for me.

Ẹbọ:
Eku, ẹja, àkùkọ, ewúrẹ́ (she goat),

Story:
Ọlọ́mọ weerewe òkè apa has been making divination
continuously but his prayers has not been granted all
his wishes were still pending. He made consultation
and he was told to make offerings to Ifá and his Ori.
He was told to ask his Ori what it wants to make his
wishes come true and he complied, he made the
offerings to his Ifá and Orí on the same day and he
did. His Ori and Ifá joined hands and brought him his
goodness and blessings to him.

Akose:
Èwe awede, use it to wash your ikins. Put the ikins
back to the container before you feed Ifa, grind the
broken remaining leaves with Ọ̀sẹ̀ and use it to bath
only your head before you offer your head whatever
you want to use for the offerings.
Ejiogbe 4.

Kaka ribiti kafibon tíì


Eruku tóóró a mọ́n yọ
Eruku así mọ taala bole
Adífáfún Ayilegbe ọrun
Nigbati ń bẹ láàrin ọ̀tá
Èyí tí ó fi alapa ṣẹ́gun ọ̀tá rẹ tutu
Ẹbọ lawo ni kowase
Ko mọ̀n wó lota pa
Ògiri alapa
Ko mọ̀n wó lota pa
Ògiri alapa
Sàngó ń báwo rẹ ṣẹ́gun.

Translation:
Let's wrap it up and push it with a gun
Makes dust to come out
And the dust covers the day
Casted Ifá for Ayilegbe ọrun
When he was dining and wining with enemies
And he will use old walls to conquer his enemies
totally
He was told to make sacrifice and he complied
Let it fall on the enemies
The old walls
Let it fall on the enemies
The old walls
Sàngó is going to conquer my enemies

Ẹbọ :
Eku, ẹja, abodie, àkùkọ 3, agbo (ram)

Story:
Unknown to Ayilegbe ọrun (the one that rolls beside
ọrun) is among enemies everyday every time. They
wished him bad every time and all the bad vibes
reacted in his life which causes him to deteriorate in
everything. He went to make consultation and he was
told that his enemies is behind his misfortunes. He
was told to make sacrifice and he complied with the
babaláwos. One day when the enemies is planning
against him beside an old wall, Èsù ọ̀dàrà made them
to stand there and Sango threw his stone to the wall
which fell on all of them. They all died at once and
Ayilegbe ọrun begins to prosper again.

Akose:
Èwe ṣẹ́gun sẹ́tẹ̀
Èwe odundun
Èwe tètè
Bitter cola on sango
Small amount of ram blood

Burn everything together and grind it to make powder.


Use with cold water or ẹ̀kọ
Last modified: 12:58 PM

You might also like