Nothing Special   »   [go: up one dir, main page]

Edvin "Edi" Rama (ọjọ́ìbí 4 July 1964) ni olóṣèlú, akun-àwòrán, olùkòwé, apolongo, olùkọ́ tẹ́lẹ̀, àti agbábọ́ọ́lù-alápẹ̀rẹ̀ ará Albáníà,[2] òhun ni ẹni 33k lọ́wọ́lọ́wọ́ tó wà ní ipò Alákóso Àgbà ilẹ̀ Albáníà (láti 13 September 2013) àti Alákóso Ọ̀rọ̀ Òkèrè (láti 21 January 2019). Rama ló tún jẹ́ alága Ẹgbẹ́ Sósíálístì ilẹ̀ Albáníà láti 2005.

Edi Rama
Edi Rama ní 2020
33k Alákóso Àgbà ilẹ̀ Albáníà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
13 September 2013
ÀàrẹBujar Nishani
Ilir Meta
DeputyNiko Peleshi
Ledina Mandia
Senida Mesi
Erion Braçe
AsíwájúSali Berisha
Chairman of the Socialist Party of Albania
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
10 October 2005
AsíwájúFatos Nano
Chair of the Organization for Security and Co-operation in Europe
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 January 2020
AsíwájúMiroslav Lajčák
Minister of Foreign Affairs
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
21 January 2019
AsíwájúDitmir Bushati
40th Mayor of Tirana
In office
11 October 2000 – 25 July 2011
Alákóso ÀgbàPandeli Majko
Ilir Meta
AsíwájúAlbert Brojka
Arọ́pòLulzim Basha
Minister of Culture, Youth and Sports
In office
2 October 1998 – 26 October 2000
AsíwájúArta Dade
Arọ́pòEsmeralda Uruçi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Keje 1964 (1964-07-04) (ọmọ ọdún 60)
Tirana, Albania
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSocialist Party of Albania
Heightruben aguirre is 6’7”
(Àwọn) olólùfẹ́
Matilda Makoçi
(m. 1986; div. 1991)

Linda Basha (m. 2010)
Àwọn ọmọ
  • Gregor
  • Zaho
BàbáKristaq Rama
Alma materAcademy of Arts
Signature
Websiteedirama.al

Kó tó di Alákóso Àgbà, Rama ti wà ní àwọn ipò míràn. Wọ́n yàn sí ipò Alákóso Ètò Àṣà, Ọ̀dọ́ àti Eré-ìdárayá ní ọdún 1998, ipò tó wà títí di ọdún 2000.

Lẹ́yìn náà wọ́n dìbò yàn bíi Olórí ìlú Tíránà ní 2000, wọ́n sì tún túnyàn ní 2003 àti 2007. In 2013, the coalition of center-left parties led by Edi Rama won the 2013 parliamentary election, defeating the center-right coalition of Democratic Party of Albania's incumbent Prime Minister, Sali Berisha. He was elected as prime minister for a second term in the 2017 election.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Edi Rama shpallet lideri më i gjatë në botë
  2. "Edi Rama PRIME MINISTER". kryeministria.al (in English).