Bimbo Manuel
Ìrísí
Bimbo Manuel | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | ọgbọ̀njọ́ oṣù Kẹwàá Ọdún 1958. Ìpínlẹ̀ Èkó |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Port Harcourt |
Iṣẹ́ | òṣèré orí-ìtàgé |
Ìgbà iṣẹ́ | 1986- di sin |
Notable work | Banana Island Ghost |
Bímbọ́ Manuel tí wọ́n bí ní ọgbọ̀njọ́ oṣù Kẹwàá Ọdún 1958. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé[1][2][3][4] tí wọ́n yàn án fún òṣèré tó peregedé jùlọ nínú amì-ẹ̀yẹ 2013 Nollywood Movies Awards ní ọdún 2013.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Bímbọ́ ní Ìpínlẹ̀ Èkó [5]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akàròyìn ní orí ìkanì rédíò ti Ìpínlẹ̀ Ògùn (OGBC) , tí ó sì tún dara pọ̀ mọ́ Ilé-iṣẹ́ amóhù-máwòrán ti Ìpínlẹ̀ Ògùn (OGT) gègẹ́ bí akàròyìn bákan náà, lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀ Eré Oníṣẹ́ ti Tíátà, ní University of Port harcourt [6] before commencing his acting career in 1986[5]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Tango with Me (2010)
- Heroes & Zeros (2012)
- Torn (2013)
- Dazzling Mirage (2014)
- Render to Caesar (2014)
- October 1 (2014)
- Heaven's Hell (2015)
- Shijuwomi (2015)[7][8][9]
- 93 Days (2016)
- Banana Island Ghost (2017)[10]
Eré orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Actor Bimbo Manuel: 'It is not simple politics they play there at the AGN. It is filthy….'". stargist.com. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Nollywood needs to produce more quality films –Bimbo Manuel". thenationonlineng.net. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "I was once paid N20 per show by NTA –Bimbo Manuel". dailyindependentnig.com. Archived from the original on 3 July 2014. Retrieved 13 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nadia vs Manuel in Zero to Hero". punchng.com. Archived from the original on 22 August 2012. Retrieved 13 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 5.0 5.1 "I have a good reputation-Bimbo Manuel". Nigerian Films. Archived from the original on December 24, 2014. Retrieved November 14, 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Segun Adebayo (May 19, 2013). "I count my success in my wife, children... —Bimbo Manuel". Nigerian Tribune. Archived from the original on December 14, 2014. https://web.archive.org/web/20141214104135/http://tribune.com.ng/news2013/index.php/en/component/k2/item/12282-i-count-my-success-in-my-wife-children-bimbo-manuel.
- ↑ "Ayo Lijadu, Bimbo Manuel lead actors in Shijuwomi". The Nation. Ozolua Uhakheme. Retrieved 22 April 2015.
- ↑ "Fast Rising Actress, Judith Audu, Veteran Actors Ayo Lijadu, Bimbo Manuel Storm Location for SHIJUWOMI". Shybell Media. Shybell Media News. Archived from the original on 26 May 2015. Retrieved 14 April 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "'Shijuwomi' Judith Audu, Ayo Lijadu and Bimbo Manuel star in new movie". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Archived from the original on 10 April 2015. Retrieved 9 April 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Banana Island Ghost Full Cast". Uzomedia. Retrieved 2017-05-20.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
Àwọn Ìtàkùn Ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ẹ̀ka:
- Pages with citations using unsupported parameters
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from July 2017
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- No local image but image on Wikidata
- 20th-century Nigerian male actors
- 21st-century Nigerian male actors
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1958
- Male actors from Lagos State
- Yoruba male actors
- University of Port Harcourt alumni
- Male actors in Yoruba cinema
- Nigerian male television actors