Àbújá
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Abuja)
Abuja | ||
---|---|---|
Adugbo Garki, Abuja | ||
| ||
Orílẹ̀-èdè | Nigeria | |
Alakoso | Adamu Aliero | |
Area | ||
• Total | 1,769 km2 (683 sq mi) | |
• Land | 1,769 km2 (683 sq mi) | |
Population | ||
• Total | 778,567 | |
• Density | 1,092.9/km2 (2,831/sq mi) | |
Website | http://www.fct.gov.ng/ |
Àbújá jẹ́ olú-Ìlú fún orílé-èdè Nàìjíríà. Ìlú yí ni ó jẹ́ àrin-gbùngbùn fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ilé ìjọba àpapọ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ní abẹ́ Aso Rock, Àpáta Agbára ni Àbújá.[1][2] [3][4]. Àbújá dí olú-ìlú orílè-ede Nàìjíríà ní osù kéjìlá, odún 1991, àkọsílẹ̀ ètò ikaniyan ti ọdún 2006 sọ wípé Àbújá ní olùgbé 776,298[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Kästle, Klaus (1991-12-12). "Google Map of the City of Abuja, Nigeria". Nations Online Project. Retrieved 2019-11-19.
- ↑ "Abuja 2019: Best of Abuja, Nigeria Tourism". TripAdvisor. 2019-11-19. Retrieved 2019-11-19.
- ↑ "The Founding of Abuja, Nigeria". Building the World. 2012-07-10. Retrieved 2019-11-19.
- ↑ "Abuja - Geography, Development, & Population". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-11-19.
- ↑ "Wayback Machine" (PDF). placng.org. 2013-03-19. Archived from the original (PDF) on 2013-03-19. Retrieved 2022-03-10. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Àbújá |